Wọn fi 'Were Olorin' jẹ oye amuludun l'Awori (Fọto) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, August 21, 2022

Wọn fi 'Were Olorin' jẹ oye amuludun l'Awori (Fọto)


Iroyin ayọ lo tun wọlé tọ àwọn ololufẹ olorin takasufe nni, Habeeb Okikiọla ti ọpọ awọn ololufẹ rẹ mọ si Portable pẹlu bi wọn ṣe fi jẹ oye tuntun.

Oye Amuludun ti Tigbo ni ilẹ Awori la gbọ pe wọn fi Portable ti awọn kan tun n pe ni Were Olorin jẹ.
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI