Ẹ tete pada si ẹnu iṣẹ, bi bẹẹ kọ... - Ile ẹjọ paṣẹ fun ASUU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, September 21, 2022

Ẹ tete pada si ẹnu iṣẹ, bi bẹẹ kọ... - Ile ẹjọ paṣẹ fun ASUU


Ile ẹjọ apapọ ti wọn pe ni National Industrial Court ti paṣẹ pe ki gbogbo awọn olukọọ ati oṣiṣẹ ile ẹkọ fasiti ti wọno wa labẹ asia ẹgbẹ Academic Staff Union of Universities (ASUU) kaakiri orileede Naijiria pada s'ẹnu iṣẹ wọn lai fi akoko ṣofo rara.
 
Oni, Ọjọru, Wẹsidee  ni ile-ẹjọ naa paṣẹ ọhun labẹ ofin ti Trade Dispute Act and National Interest, abala kejidinlogun sọ pe ki gbogbo wọn pada sẹnu iṣẹ.

Nigba to n gbe idajọ naa kalẹ, Onidajọ Polycap Hamman paṣẹ pe ki iyanṣẹlodi naa d'opin ni kiakia.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI