Eto ọjọ iwaju rere ni Gomina AbdulRazaq ni fun ipinlẹ Kwara - Ajakaye - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, September 11, 2022

Eto ọjọ iwaju rere ni Gomina AbdulRazaq ni fun ipinlẹ Kwara - Ajakaye


Akọwe iroyin Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara, Rafiu Ajakaye ti sọ pe erongba ọga ohun fun ipinlẹ naa ṣoju ṣaara, ko ni awuruju ninu, bi ko ṣe pe nipa itẹsiwaju ati ọjọ iwaju rere ni.
 
Ninu apilẹkọ ti Rafiu Ajakaye fi sita laipẹ yii, lo ti yannanaa diẹ lara awọn erongba ati ipinnu gomina f'awọn eeyan kaakairi agbaye, paapaa awọn idagbasoke alailẹgbẹẹ to ti waye n'ipinlẹ Kwara laaarin ọdun mẹta.
 
Ajakaye ni ojoojumọ ni Gomina AbdulRazaq n sọ nipa awọn eto to ni f'awọn araalu nita gbangba ati ni kọọrọ, to si n f'awọn eeyan lanfaani lati sọ ohun ti wọn n fẹ.
 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI