Ile alaja jọna l'Ekoo - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, October 4, 2022

Ile alaja jọna l'Ekoo


Se ni ariwo ikunlẹ abiyamọ tun sọ laaarọ oni lagbegbe Adebayọ Makaolu to wa ni Anthony Village, ipinlẹ Eko nigba ti wọn sọ pe ile alaja kan to wa lagbegbe naa jona.
 
Okan lara awọn to n gbe lagbegbe naa lo gbe fọnran ile to n jona lọwọ ọhun sita lori ikanni ayelujara, nibi to ti n rawọ ẹbẹ s'awọn ẹlẹyinju aanu fun iranlọwọ.
 
Titi di asiko ti a pari akojọpọ iroyin yii la ko tii le f'idi ohun to ṣokunfa ijamba ina naa mulẹ.

Fidio

 


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI