AbdulRazhaq Jiddah di oludamọran pataki fun gomina Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, November 28, 2022

AbdulRazhaq Jiddah di oludamọran pataki fun gomina Kwara


Lonii, ọjọ Aje, Mọnde ni ijọba ipinlẹ Kwara kede AbdulRazhaq Abubakar Jiddah gẹgẹ bi oludamọran pataki fun Gomina AbdulRahman AbdulRazaq lori ọrọ iṣẹ to ṣe pataki, iyẹn Special Duties.

Abdul-Razhaq Abubakar Jiddah ni alaga ẹka ileeṣẹ to n ri sọrọ eto ayika, iyẹn Environmental Task Force ni ọfiisi gomina, ipinlẹ Kwara.

Gbajugbaja oniṣowo ni Jiddah jẹ niluu Ilọrin, to si tun jẹ ọkan pataki lara awọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI