Gbajumọ ọmọ ẹgbẹ oṣelu SDP ni Kwara fẹgbẹ silẹ, o loun ti ba APC lọ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, November 6, 2022

Gbajumọ ọmọ ẹgbẹ oṣelu SDP ni Kwara fẹgbẹ silẹ, o loun ti ba APC lọ


Ọkan pataki lara awọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu Social Democratic Party, SDP, Abdulmajeed Hamza Dọlapọ ti kọwe s'awọn alakoso ẹgbẹ wi pe oun ko ṣẹgbẹ naa mọ.
 
Dọlapọ, ẹni to ti figba kan ri jẹ oludije s'ipo oṣelu ninu ẹgbẹ naa lo kọwe f'ẹgbẹ silẹ ninu awọn iwe meji to tẹ wa lọwọ lọtọọtọ.
 
Lẹta naa to tẹ wa lọwọ ree:

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI