Ẹ tun wo oju iyaale ile to dawati nipinlẹ Ogun - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, January 12, 2023

Ẹ tun wo oju iyaale ile to dawati nipinlẹ Ogun


Fọto ti ẹ n wo yii ni obinrin kan ti a gbọ pe wọn n wa lati ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, iyẹn latigba to ti jade nile.
 
Ogunṣanu Ọlaitan ni wọn pe orukọ obinrin naa.
 
Wọn ni latigba to ti jade nile ni irọlẹ ọjọ Aje, Mọnde ni ko ti pada sile.
 
Gbogbo akitiyan ti wọn l'awọn mọlẹbi rẹ ṣe lati rii lo ja si pabo, eyi lo jẹ ki wọn lọ fi to ileeṣẹ ọlọpaa leti.
 
Fun ẹnikẹni to ba kofiri obinrin naa, ko tete fi to ileeṣẹ ọlọpaa leti, tabi ki wọn pe awọn ẹrọ ibanisọrọ wọnyii 08122325019, 09159719271.No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI