Nitori Ronaldo, ẹgbẹ agbabọọlu Al-Nassr fi ọna ile han Aboubakar - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, January 9, 2023

Nitori Ronaldo, ẹgbẹ agbabọọlu Al-Nassr fi ọna ile han Aboubakar


Ẹgbẹ agbabọọlu Al-Nassr ti ilẹ Saudi Arabia ti juwe ọna ile fun Vincent Aboubakar, nitori bi wọn ṣe tọwọ bọwe adehun pẹlu Cristiano Ronaldo.
 
A gbọ pe kii ṣe pe wọn le Aboubakar danu, bi ko ṣe pe wọn jọ tọwọ bọwe adehun laaarin ara wọn, ti wọn si san gbogbo owo to yẹ fun un, ko to di pe wọn juwe ọna ile fun un.
 
Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, wọn ni lara awọn idi pataki ti wọn fi sọ pe ki Aboubakar maa lọ ni ti ofin ti ilẹ Saudi Arabia fi kalẹ wi pe agbabọọlu ilẹ okeere ko gbọdọ ju mẹjọ lọ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI