Ori ko awọn eeyan yọ ninu ijamba mọto l'Abẹokuta - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, January 15, 2023

Ori ko awọn eeyan yọ ninu ijamba mọto l'Abẹokuta


Ọkọ ayọkẹlẹ Toyota Camry to ni nomba idanimọ KJA 943 DC loun pẹlu ọkọ taisi Micra ti nọmba idanimọ tiẹ jẹ TRE 942 YJ jọ fori gba ara wọn.

Iwaju ile epo kan ti wọn pe ni Muyad, eyi to wa lagbegbe Mile 2, Ogun Radio, ijọba ibilẹ Abẹokuta North ni ijamba ọhun ti waye lọjọ Abamẹta, Satide to kọja.


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI