Asiko Olọrun kii pẹ - Adeniyi Johnson sọrọ lẹyin ọdun meje toun pẹlu Ṣeyi Ẹdun ti n wa ọmọ, ki wọn too bi ibeji - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, February 28, 2023

Asiko Olọrun kii pẹ - Adeniyi Johnson sọrọ lẹyin ọdun meje toun pẹlu Ṣeyi Ẹdun ti n wa ọmọ, ki wọn too bi ibeji


Gbajugbaja oṣere Yoruba nni, Adeniyi Johnson ti fi idunnu rẹ han lori ibeji ti iyawo rẹ, Ṣeyi Ẹdun ṣẹṣẹ bi lọjọ Aje, Mọnde, ana, ọjọ kẹtadinlọgbọn, oṣu keji, ọdun 2023.
 
Kaakiri agbaye lawọn ololufẹ awọn ilu mọ-ọn-ka oṣere tiata ọhun ti n ki wọn ku oriire lori ayọ ọmọ tuntun yii.
 
Alẹ ana naa ni Adeniyi Johnson gbe ọrọ idupẹ sori ikanni Insitagiraamu rẹ wi pe 'Asiko Ọlọrun kii pẹ', ati pe ipinnu Ọlọrun fun ẹda laye ga pupọ.
 
Adeniyi Johnson and Seyi Edun's maternity shoot

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI