Ọkan pataki lara awọn oloye to di ilu Owu-Ẹgba, Oloye Oluwọle Iṣhọla ti jade laye.
Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, Oloye Oluwọle Iṣhọla ni Abọre ilu Owu, to si tun jẹ Oluwo Iledi-Owu, Abẹokuta lo jade laye lọjọ Aiku, Sannde ana.
Oloogbe naa ti ọpọ mọ si Baba Oriṣa Agbaye ni wọn lo jade laye lẹyin aisan arampẹ.
No comments:
Post a Comment