Ṣọọṣi ni Temitọpẹ Ọlọjẹde lọ ja lole, kI ọwọ Amọtẹkun too tẹ ẹ l'Oṣogbo - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, February 12, 2023

Ṣọọṣi ni Temitọpẹ Ọlọjẹde lọ ja lole, kI ọwọ Amọtẹkun too tẹ ẹ l'Oṣogbo


Ṣikun bayii lọwọ palaba baale ile, ẹni ọdun mọkanlelogoji kan, Temitọpẹ Ọlọjẹde, ẹni ti wọn ni ko niṣẹ meji ju idigunjale lọ niluu Oṣogbo, ipinlẹ Ọṣun segi sọwọ ẹṣọ aabo Amọtẹkun.
 
Temitọpẹ ni iroyin fi to wa leti pe o wọ ṣọọṣi kan to wa lagbegbe Ogo-Oluwa, iyẹn niluu Oṣogbo, to si lo ja wọn lole nibẹ.
Operatives of Osun Amotekun corps have arrested a 41-year-old man, Temitope Olojede for suspected theft.
Olojede was arrested on Thursday after operatives received a distress call from residents that he had robbed a church at the Ogo-Oluwa area of Osogbo.
Confirming the arrest to journalists in Osogbo on Saturday, the Osun Amotekun Corps Commander, Brigadier General Bashir Adewinmbi described the suspect as a known culprit who has been terrifying the residents of Ogo-Oluwa Area, Osogbo.
“Our men received a distress call from one of the residents of Ogo-Oluwa that a church was burgled and they needed the attention of the operatives urgently to arrest the felon; they swung into action immediately and he was arrested after trying to circumvent the scene.
“During investigation, he confessed to being in the act for a very long time and that he has been stealing from the area and its environs,” Adewinmbi asserted.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI