Ọkọ reluwee run bọọsi ijọba Eko womuwomu, ọpọ ẹmi lo ṣofo danu (Fọto) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, March 9, 2023

Ọkọ reluwee run bọọsi ijọba Eko womuwomu, ọpọ ẹmi lo ṣofo danu (Fọto)


Ariwo Ikunlẹ abiyamọ lo gba ẹnu awọn ara agbegbe Ikẹja to wa nipinlẹ Ekoo kan laarọ ana, Ọjọru, Wẹsidee nigba ti ọkọ reluwee kọlu bọọsi akero ijọba, to si dẹmi ọpọ awọn eeyan legbodo.

Bọọsi akero nla ti nọmba idanimọ rẹ jẹ 04A- 48LA ni wọn sọ pe o pade agbako naa lakoko toun pẹlu ọkọ reluwee fori gbari, tiyẹn si run un womuwomu.













No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI