Aye o! Ààfin Ọọni Ile Ifẹ jona di eeru - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, April 29, 2023

Aye o! Ààfin Ọọni Ile Ifẹ jona di eeru


Ìjàmbá iná selẹ ni Afin Ọọ́ni Ilé-Ifè látàrí iná eletiriki

Ọkàn lára àwọn ilé gbígbé tó wà laarin agbala Aafin Ooni ile Ife ni ìṣẹ̀lẹ̀ náà sele ni nkan bi aago mọkanla abọ alẹ ana ni ina jó, ti isẹlẹ naa waye nipasẹ awọn ohun elo itanna inú ààfin.

Ina naa ko tan kaakiri ilé tó kú yàtò sì apákáǹ ti o jóná lára àwọn ilé gbígbé tó wà nínú ààfin nípasẹ̀ akitiyan àwọn ilé ìṣe ìjọba tó ohùn mojuto ìṣẹ̀lẹ̀ iná tí OAU. 

Otunba Moses Olafare, Oludari ètò ìròyìn fún Ooni ile Ife fìdí ìṣẹ̀lẹ̀ náà múlè pé ẹnikẹ́ni ó fi ara pá ninu ìjàmbá iná náà.

Fọto





No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI