O ma ṣe o! Murphy Afọlabi, gbajugbaja ossere tiata jade laye - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, May 14, 2023

O ma ṣe o! Murphy Afọlabi, gbajugbaja ossere tiata jade laye


Iroyin yajoyajo to tẹ AWIKONKO lọwọ laipẹ yii ti fidi rẹ mulẹ pe gbajugbaja oṣere tiata nni, Murphy Afọlabi ti jade laye.

Oni ọjọ Aiku, Sannde la gbọ pe Afọlabi jade laye, lẹyin to ṣubu ni baluwẹ.

Ẹkunrẹrẹ iroyin n bọ laipẹ

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI