Anfaani Ọtun: Bi o ṣe le gba ẹran Agbo Ileya ọfẹ lai laagun jinna - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, June 22, 2023

Anfaani Ọtun: Bi o ṣe le gba ẹran Agbo Ileya ọfẹ lai laagun jinna


Njẹ iwọ n wa ọna lati di lanlọọdu, ki o si tun ṣayẹyẹ ọdun Ileya pẹlu mọlẹbi rẹ pẹlu ẹran agbo Ileya ọfẹ?
 
Gbogbo eto olo ti to bayii ni ileeṣẹ akọkọ lorileede Naijiria to mọ nipa bi wọn ṣe le sọ ayalegbe di ojulowo lanlọọdi lai daamu, ni ibamu pẹlu ilana ati ofin ile gbigbe lorileede Naijiria. 
 
Odu ni ileeṣẹ Adron Homes and Properties Limited, kii ṣaimọ f'oloko nibi ka ta ilẹ, ile ati dukia ni irọrun.
 
Bi ayẹyẹ pọpọṣinṣin ọdun Ileya ṣe wọle de, Ileeṣẹ Adron Homes lawọn ti ṣetan lati sọ ọpọ ayalegbe di lanlọọdu ni irọrun.
 
Ninu atẹjade ti awọn alakoso ileeṣẹ naa fi sita laipẹ yii, wọn ni gbogbo owo ilẹ wọn lawọn ti ja wa silẹ patapata, fun awọn eeyan lati di onile ara wọn, ki wọn si kuro ninu ẹgbẹ awọn to n ya ile gbe kaakiri.
 
Eto ọhun to bẹrẹ ni nnkan bi ọsẹ meloo kan sẹyin, eyi ti wọn pe ni 'ILEYA RẸPẸTẸ' ni ileeṣẹ Adron Homes ti sọ pe awọn ti ja iye owo ti wọn n ta awọn ilẹ wọn n'ipinlẹ Ekoo, Ogun, Ọṣun, Ọyọ, Ekiti, Niger, Nasarawa ati Abuja wa silẹ patapata.

Awọn ilẹ naa ni wọn lawọn ti yọ ida ọgbọ, ida ogoji ati ida aadọta kuro ninu iye owo ti wọn n ta awọn ilẹ naa kaakiri, lati le jẹ k'awọn eeyan n'ipin ninu anfaani rẹpẹtẹ yii.

AWIKONKO gbọ pe san-an diẹ-diẹ ni awọn owo ilẹ yii kaakiri gbogbo ibi ti wọn ni ilẹ si lorileede Naijiria.
 
Iyẹn nikan tun kọ, gbogbo awọn onibara tuntun ati tẹlẹ la gbọ pe bi wọn ṣe n kopa ninu anfaani ọtun yii, wọn yoo tun lanfaani lati gba oriṣiriṣi ẹbun bii Agbo Ọdun Ileya, Ogunfe, Apo Irẹsi, Faanu igbalode ati awọn ẹbun miran bii Rechargeable fans, Home Theatres, Water Dispensers, Electric Kettles, Refrigerators, Food Processors, Vacuum Cleaners, Cooking Oil, Gas Burners, Mini Food Packs, Washing Machines, Deep Freezers, Smart TVs, Generators ati bẹẹbẹẹlọ.
 
Ki lẹ n duro de, ẹ le ba awọn alaṣẹ ileeṣẹ Adron Homes sọrọ lori awọn ikanni ayelujara bii Facebook Adronhomesofficial; Twitter @adronhomes; ati Instagram @adronhomesofficial tabi ki ẹ lọ si ikanni www.adronhomesproperties.com.






No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI