Ayẹyẹ ọjọ ibi: AbdulRazaq ba Sẹnetọ Sadiq Umar yọ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, June 8, 2023

Ayẹyẹ ọjọ ibi: AbdulRazaq ba Sẹnetọ Sadiq Umar yọ


Gomina AbdulRahman Abdulrazaq ti ipinlẹ Kwara ti ba Sẹnetọ to n ṣoju ẹkun Ariwa ipinlẹ naa nile igbimọ aṣofin agba l'Abuja, Sẹnetọ Sadiq Umar fun ti ayẹyẹ ọjọọbi ọdun mẹtalelaadọta to n ṣe lonii, Ọjọbọ tii ṣe Tọsidee.

Ninu atẹjade ti gomina fi ki agba oloṣelu naa, o ni adari rere to ṣee fọkan tan, ti awọn iwa adari tẹ awọn eeyan lọrun ni.

O wa gbe oṣuba rabandẹ fun Sẹnetọ Umar lori awọn iṣẹ takuntakun to ti ṣe siluu

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI