Gbajabiamila di olori awọn oṣiṣẹ Aarẹ Tinubu - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, June 1, 2023

Gbajabiamila di olori awọn oṣiṣẹ Aarẹ Tinubu


Aarẹ Bọla Ahmẹd Tinubu ti kede abẹnugọn ile igbimọ aṣoju-ṣofin Naijiria, Ọnarebu Fẹmi Gbajabiamila gẹgẹ bi olori awọn oṣiṣẹ rẹ.


Tinubu lo kede Gbajabiamila gẹgẹ bi olori awọn oṣiṣẹ rẹ lonii, Ọjọbọ tii ṣe Tọsidee niluu Abuja, lakoko to n ṣe ipade pọ pẹlu awọn olori awọn eleto aabo ni Naijiria.

Ekunrẹrẹ iroyin naa n bọ laipẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI