Titi di asiko ti a pari akojọpọ iroyin yii l'awọn oṣiṣẹ ijọba to fi mọ awọn akẹkọọ patapata kaakiri ipinlẹ Kwara ṣi fi n jẹ igabdun igbokegbodo ọkọ ọfẹ to n gbe wọnlọ si ibi-iṣẹ ati ile-ẹkọ.
Eto yii ni Gomina AbdulRahman AbdulRazaq gbe kalẹ lati fi mu irọrun ba awọn oṣiṣẹ ati akẹkọọ lori owo epo bẹntiroolu to lọ soke, lẹyin ti ijọba apapọ kede yiyọ owo iranwọ ori epo ti a mọ si 'subsidy' kuro.
Diẹ ree lara awọn fọto to f'idi rẹ mulẹ...
No comments:
Post a Comment