Gomina ipinle Kwara, to tun jẹ alaga ẹgbẹ awọn gomina lorileede Naijiria, AbdulRahman AbdulRazaq ti darapọ mọ ayajọ ọjọ awọn ọmọ ilẹ Faranse, ẹyi ti wọn ṣagbekalẹ rẹ niluu Abuja l'ọjọ Ẹti, Furaide to kọja yii.
Aṣoju ilẹ Faranse si Naijiria, Ambasadọ Arabinrin Emmanuelle Blatmann lo gbe akanṣe eto ayẹyẹ naa kalẹ niluu Abuja.
Lara awọn to si wa nibẹ ni Gomina AbdulRazaq.
No comments:
Post a Comment