Anfaani nla f'awọn to fẹẹ ṣiṣẹ agbẹ ati ọgbin nirọrun lọna igbalode ree - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, July 19, 2023

Anfaani nla f'awọn to fẹẹ ṣiṣẹ agbẹ ati ọgbin nirọrun lọna igbalode ree


Njẹ iwọ n wa ọna lati ṣiṣẹ agbẹ ati ọgbin lọna igbalode, anfaani nla lo delẹ yii fun ọ lati darapọ mọ idanilẹkọọ ọlọjọ meji to fẹẹ waye yii.
 
Ileeṣẹ kan ti wọn pe ni Agricultural and Rural Management Training Institute, ARMTI lo gbe idanilẹkọọ naa kalẹ lati fi ran awọn eeyan lọwọ.
 
Ọjọ karundinlọgbọn si ọjọ kẹrindinlọgbọn, oṣu keje, ọdun ti a wa yii ni idanilẹkọọ ọhun yoo waye.
 
Oriṣiriṣi idanilẹkọọ l'awọn akopa yoo gba, eyi ti yoo jẹ ki wọn le ṣiṣẹ agbẹ ati ọgbin wọn ni irọrun.
 
Lati fi orukọ silẹ, ẹ lọ si ikanni https://forms.gle/gMPYuKR7Y1DWMkeF9

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI