Awọn agba Aafa rọjo adura le AbdulRazaq lori lọjọ Aiku, Sannde - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, July 23, 2023

Awọn agba Aafa rọjo adura le AbdulRazaq lori lọjọ Aiku, Sannde


Agbarijọ awọn agba Aafa niluu Ilọrin, ipinlẹ Kwara ti rọjo adura le Gomina AbdulRahman AbdulRazaq lori lonii, ọjọ Aiku, Sannde.

Lara awọn agba Aafa to wa ni Yidi NASFAT to wa niluu Ilọrin ni Imaamu agba fun NASFAT, nipinlẹ naa, Alaaji Abdullahi Alaya; akọwe awọn agbaagba NASFAT, Alaaji Abdulganiu Ọba; Agbẹnusọ ẹgbẹ awọn agbaagba, Alaaji Ahmẹd Adio; alaga NASFAT, ẹka tiluu Ilọrin, Alaaji Abdulakeem Abimbọla Yusuf, ati awọn miran.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI