O ma ṣe o! Mọto pa akẹkọọ Olabisi Onabanjọ danu - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, July 21, 2023

O ma ṣe o! Mọto pa akẹkọọ Olabisi Onabanjọ danu


Ọjọ buruku, eṣu gbomimu lọjọ kẹẹdogun, oṣu keje, ọdun 2023 yii jẹ n'ipinlẹ Ogun, paapaa niluu Agọ-Iwoye, nigba ti wọn sọ pe mọto ayọkẹlẹ kan gba akẹkọọ fasiti Ọlabisi Ọnabanjọ, to si gbabẹ ku loju ẹsẹ.

Akẹkọọ naa ti ọpọ awọn eeyan mọ si Sẹnetọ Yhanex ni ẹka ikẹkọọ Administrative and Management Sciences.
 
Ohun ti a gbọ ni pe asiko ti ọmọkunrin naa fẹẹ lọ ran nnkan ni mọto ọhun gba a danu, to si gbabẹ dagbere faye.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI