Aarẹ Tinubu balẹ si ilẹ olominira Bẹnin pẹlu awọn gomina mẹfa (Fọto) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, August 3, 2023

Aarẹ Tinubu balẹ si ilẹ olominira Bẹnin pẹlu awọn gomina mẹfa (Fọto)


Aarẹ Bọla Ahmẹd Tinubu balẹ si ilẹ olominira Bẹnin lati darapọ mọ wọn fun ayẹyẹ ayajọ igbominira ọdun kẹtalelọgọta ti wọn ṣe.

Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii ni Aarẹ Tinubu lọ ba ilẹ olominira Bẹnin naa ṣayẹyẹ yii pẹlu awọn gomina mẹfa lati Naijiria ti wọn kọwọrin pẹlu ẹ.
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI