Awọn alẹnulọrọ l'ẹkun Ajikobi, Alanamu ṣabẹwọ s'AbdulRazaq n'Ilọrin (Fọto) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, August 27, 2023

Awọn alẹnulọrọ l'ẹkun Ajikobi, Alanamu ṣabẹwọ s'AbdulRazaq n'Ilọrin (Fọto)


L'Ọjọbọ tii ṣe Tọsidee to kọja yii l'awọn agbaagba niluu Ilọrin, ipinlẹ Kwara ṣabẹwo si Gomina AbdulRahman AbdulRazaq, lati kii ku iṣẹ takuntakun to n ṣe nipa eto idagbasoke ati ilọsiwaju ipinlẹ naa lapapọ.
 
Lara awọn to lọ ṣabẹwo ọhun ni Alaaji Adefalu Lawal; Alaaji Mustapha Kobe; Alaaji Zubair Olosasa; ati Ọnarebu Abdulgafar Olayemi Ayinla Ayilara.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI