Ẹ wo orukọ awọn Kọmiṣanna ti yoo ba AbdulRazaq ṣiṣẹ lẹẹkeji ni Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, August 15, 2023

Ẹ wo orukọ awọn Kọmiṣanna ti yoo ba AbdulRazaq ṣiṣẹ lẹẹkeji ni Kwara


Ile igbimọ aṣofin ipinlẹ Kwara ti gbe orukọ awọn ti Gomina AbdulRahman AbdulRazaq dabaa lati b a ṣiṣẹ papọ gẹgẹ bii kọmiṣanna fun saa iṣejọba rẹ keji.

1. Abdulganiyu AbdulAzeez – Asa
2. Hon. Aliyu Kora Sabi – Baruteen
3. Sheu Ndanusa Usman – Edu
4. Afolasade Opeyemi Kemi – Ekiti
5. Dr. Segun Ogunsola – Ifelodun
6. Abdulquawiy Olododo - Ilorin East
7. Sa'adatu Modibbo-Kawu - Ilorin South
8. Senior Ibrahim Suleiman - Ilorin West
9. Hauwa Nuru - Ilorin West
10. Damilola Yusuf - Isin
11. Oloruntoyosi Thomas - Isin
12. Bola Olukoju - Irepodun
13. Hon. Abubakar Abdullahi Bata - Kaiam
14. Bello John Olanrewaju - Moro
15. Dr. Amina El-Imam - Offa
16. Dr. Mary Arinde - Oke-Ero
17. Olaitan Buraimoh - Oyun
18. Usman Yunusa - Patigi

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI