Gomina AbdulRazaq ṣabẹwo ibanikẹdun sile Latinwọ to ku s'oke okun - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, August 17, 2023

Gomina AbdulRazaq ṣabẹwo ibanikẹdun sile Latinwọ to ku s'oke okun


Gomina Abdulrahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara ti ṣabẹwo ibanikẹdun si awọn mọlẹbi Oloogbe Salaudeen Adebọla Latinwọ Laro niluu Ọffa.

Oloogbe Latinwọ Laro ni olori ipinlẹ naa lakoko ijọba ologun.

Gẹgẹ bí a ṣe gbọ, opin ọsẹ to kọja yii ni Latinwọ, ẹni to dari ipinlẹ Kwara laaarin oṣu kinni, ọdun 1984 si oṣu kẹjọ ọdun 1985 jade laye.
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI