#IjọbaMẹkunu: Aridaju b'awọn eeyan ṣe n gba owo iranwọ ni Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, August 17, 2023

#IjọbaMẹkunu: Aridaju b'awọn eeyan ṣe n gba owo iranwọ ni Kwara


"Irọ ni, ko le ri bẹẹ, ẹtanjẹ lasan ni", wọnyi lohun ti awọn alaimọkan n sọ tẹlẹ nigba ti ijọba ipinlẹ Kwara kede pe awọn ti bẹrẹ sii san owo iranwọ fun araalu, paapaa awon ọlọja at'awọn olokoowo kekeeke.

Irọ ati ahesọ naa lo ti wa pada di otitọ bayii, nigba ti awọn to n jẹ anfaani naa bẹrẹ sii fi àrídájú bi wọn ṣe n gba owo naa han.

Wọnyii ni awọn aridaju bi awọn eeyan ṣe ti bẹrẹ sii gba owo iranwọ naa ti ileeṣẹ Kwara State Social Investment Programme (KWASSIP) ṣagbatẹru sisan rẹ.



No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI