Fọto: Ijọba Kwara pari opopona ilu Afon n'ijọba ibilẹ Asa - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, October 11, 2023

Fọto: Ijọba Kwara pari opopona ilu Afon n'ijọba ibilẹ Asa


Ijọba ipinlẹ Kwara labẹ iṣakoso Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti pari akanṣe iṣẹ opopona to wa ni ilu Afọn, ijọba ibilẹ Asa, ipinlẹ naa fun lilo ati igbokegbodo ọkọ ti yoo mu irọrun ba araalu.
 
Ọkan pataki lara awọn opopona ti ijọba AbdulRazaq dawọ le ree latigba to ti wa lori ipo naa.
 
Eyi, gẹgẹ bi a ṣe gọ, yoo tun kopa ninu idagbasoke eto ọrọ aje ipinlẹ naa.
 
#Isenlo


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI