Ṣé lóòótọ́ ni òṣèrébìnrin nnì, Bíọ́lá Báyọ̀ ti darapọ̀ mọ́ iṣẹ́ ológun? (Fọ́tò) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, October 23, 2023

Ṣé lóòótọ́ ni òṣèrébìnrin nnì, Bíọ́lá Báyọ̀ ti darapọ̀ mọ́ iṣẹ́ ológun? (Fọ́tò)


Pupọ awọn ti wọn n ri fọto yii ni wọn n sọ pe iṣẹ ologun yẹ Biọla Bayọ pupọ, pẹlu bi aṣọ ologun to wọ ṣe ṣe rẹgi lara rẹ.

Ẹ gbọ, ninu iṣẹ tiata ati iṣẹ ologun, ewo lẹ fẹ ko tẹsiwaju nidi rẹ?


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI