Ẹgbẹ oṣelu Labour ti sọ pe ko si otitọ ninu awuyewuye to n kaakiri wi pe awọn ti bẹrẹ ipade lati darapọ mọ ẹgbẹ oṣelu kan, to si ni irọ to jinna si otitọ ni.
Akọwe ipolongo ẹgbẹ naa, Obiora Ifoh lo sọrọ yii ninu atẹjade to fi lede lonii, Ọjọbọ, Tọside niluu Abuja.
O ni iroyin ẹlẹjẹ naa ti wọn gbe sita ni lati fi da ẹlẹya awọn silẹ nigboro.
No comments:
Post a Comment