Lojuna lati jẹ ki eto ẹkọ nipinlẹ Kwara ba ti igbalode mu, ijọba ipinlẹ naa tun ti fun awọn Tiṣa miran ni awọn irinṣẹ igbalode amuṣẹya ti a mọ si 'Tablet', iyẹn foonu igbalode.
Lara awọn akanṣe eto agbekalẹ ti yoo mu ki eto ẹkọ ni ilọsiwaju ati lati ba ẹgbẹ pe, eyi ti wọn pe ni #KwaraLEARN ni bi ijọba ṣe n pin awọn irinṣẹ amuṣẹya naa.
No comments:
Post a Comment