Njé o ti wo 'A Tribe Called Judah' ? - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, January 18, 2024

Njé o ti wo 'A Tribe Called Judah' ?


Sinima agbelewo ti aye n pokiki rẹ gidi lasiko yii ni A Tribe Called Judah, eyi ti gbajugbaja Funkẹ Akindele ṣe sita.
 
Warawara ni awọn eeyan n wo fiimu ọhun kaakiri agbaye, ti yoo si gba aami ẹyẹ laipẹ.
 
Download

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI