O tan o! Igboho pada wọ Naijiria - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, February 22, 2024

O tan o! Igboho pada wọ Naijiria


Orin, ilu ati ijo ni awọn ololufẹ gbajugbaja ajafẹ ọmọ Yoruba nni, Oloye Sunday Adeniyi Adeyẹmọ ti ọpọ mọ si Sunday Igboho fi pade rẹ lonii, Ọjọbọ, Tọside.

Ninu fọnran kan ti agbẹnusọ rẹ, Ọlayẹmi Koiki gbe sori ikanni ayelujara 'X' rẹ lo ti jẹ ko di mimọ pe Igboho ti pada si Naijiria.

Igboho wọ ilu Ibadan lati ṣe oku mama rẹ to jade laye lọdun to kọja.

Ẹkunrẹrẹ iroyin n bọ laipẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI