Aarẹ Tinubu, Shettima, AbdulRazaq nibi irun Jimọ to kọja - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, April 14, 2024

Aarẹ Tinubu, Shettima, AbdulRazaq nibi irun Jimọ to kọja


Lọjọ Ẹti, Furaidee, ọsẹ to ṣẹṣẹ pari yii ni Aarẹ orileede Naijiria, Bọla Ahmẹd Tinubu, igbakeji rẹ, Kashim Shettima ati awọn bii Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara ni wọn kirun Jimọ.

Mọṣalaṣi agba ti Dolphin Estate Central Mosque la gbọ pe wọn ti kirun yii.

Gomina AbdulRazaq lo lewaju wọn lọ, gẹgẹ bi iroyin to tẹ wa lọwọ ṣe sọ.

Awọn aworan ree
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI