Iroyin ayọ! Owo baagi irẹsi ja wa silẹ patapata ni Kwara, ₦54,000 ni wọn n ta bayii - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, April 19, 2024

Iroyin ayọ! Owo baagi irẹsi ja wa silẹ patapata ni Kwara, ₦54,000 ni wọn n ta bayii


Iroyin to n lọ kaakiri igboro ipinlẹ Kwara bayii ni pe owo irẹsi ti ja lọ silẹ patapata si iye owo ti wọn n ta tẹlẹ.

Eyii lo si fa idunnu araalu wi pe igba ọtun ti n bọ diẹdiẹ.

Tẹlẹtẹlẹ, ẹgbẹrun lọna ọgọrin naira ni wọn n ta baagi irẹsi tẹlẹ, ṣugbọn ni bayii, ẹgbẹrun mẹrinlelaadọta ni wọn n ta a, gẹgẹ bi a ṣe gbọ 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI