Ijọba ipinlẹ Kwara ti sọ pe opopona Township Hall si Igbaja ti de ipele to ti fẹẹ pari fun lilo araalu.
Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, wọn ni ọda dudu to gbẹyin ni wọn yoo da lonii.
Opopona naa yoo mu irọrun ba igbokegbodo ọkọ ati idagbasoke ba eto ọrọ aje ipinlẹ Kwara.
No comments:
Post a Comment