Jẹ ki igbesi aye rẹ tẹsiwaju pẹlu anfaani VIDCO SERIES ti ileeṣẹ Adron Homes gbe kalẹ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, April 19, 2024

Jẹ ki igbesi aye rẹ tẹsiwaju pẹlu anfaani VIDCO SERIES ti ileeṣẹ Adron Homes gbe kalẹ


Bi wọn ba n sọ nipa awọn anfaani ọtun ti ko wọpọ, eyi ti awọn eeyan n jẹ lasiko yii, ko pe meji rara bi ko ṣe ti VIDCO SERIES ti gbajugbaja ileeṣẹ Adron Homes ṣagbekalẹ rẹ.

Ewo tun ni VIDCO SERIES abi?

Ohun ni anfaani nla ti awọn eeyan ti wọn ni ipinnu lati di onile lori n jẹ nileeṣẹ Adron Homes and Properties Limited lọwọlọwọ.

Ile adagbe oni yara meji, iyẹn 2-Bedroom Terrace Apartments to kun fun ọpọlọpọ ohun igbadun igbalode ti yoo mu ẹmi gun.

Lara awọn igbadun to wa nibẹ ni aaye ati agbegbe igbafẹ ti oloyinbo n pe ni recreational grounds, aaye ibi ti ẹ ti le gba bọọlu alafẹsẹgba ati alafọwọgba, iyẹn Basketball.

Bakan naa tun ni ọja igbalode wa nibẹ pẹlu, leyi ti ko ni jẹ ki ẹ maa daamu lati ra ohunkohun, yala ohun elo tabi ti jijẹ.

Kii ṣe ti ẹnu, fun awọn to ba fẹẹ di lanlọọdu, ti wọn si fẹẹ pẹ laye, VIDCO SERIES ni ki ẹ gba lọ lati lọ jẹ anfaani yii.

Owo ti ko ga ni lara rara ni ileeṣẹ Adron Homes gbe anfaani yii kalẹ fun awọn onibara wọn atijọ ati tuntun.

Fun alaye ibeere tabi lẹkunrẹrẹ, awọn ẹrọ ibanisọrọ yii ni ki ẹ pe 08022122490, 07055277727, 08023781123, 08023236621. Bakan naa lẹ tun le lọ soju opo ayelujara wọn ni 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI