Sẹnetọ Tanko Al-Makura di alakoso agba fun ajọ UBEC - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, July 2, 2025

Sẹnetọ Tanko Al-Makura di alakoso agba fun ajọ UBEC


Aarẹ Bola Ahmed Tinubu ti buwọ lu iyansipo Gomina tẹlẹri nipinle Nasarawa, Sẹnetọ Umaru Tanko Al-Makura gẹgẹ bi alaga igbimọ iṣakoso ajọ Universal Basic Education Commission (UBEC) lorileede Naijiria.

Minisita f'ọrọ eto ẹkọ, Tunji Alausa lo fi ikede maa sita nibi ifilọlẹ akanṣe iṣẹ AFD-supported ICT Development Project to waye laipẹ yii.

Ẹkunrẹrẹ nbọ laipẹ 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI