Perfect Woman ti jade o - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, November 6, 2017

Perfect Woman ti jade o

Ko si orin meji tawon to ja si orin taka-sufe (hiphop) tun n gbo bayii, bi ko se eyi ti won pe ni Perfect Woman, iye Obinrin To Pe.

Okan lara awon irawo olorin to sese n dide bo l’orileede Naijiria lo ko orin naa lati fi gboriyin fawon obinrin wa. Orin to ko awon eeyan lekoo repete ni.

Awon to ba gbo o nikan lo le ye; Awon ibi ti e ti le rii gbo (download) ni won yii;

 Bakan naa ni orin min in ti won pe ni Bojan - Cypher naa tun jade pelu e; eyi lawon ibi ti e ti le rii download


1 comment:

  1. Davido – A Good Time Album https://trendsfox.ng/davido-a-good-time-album/

    ReplyDelete

PÍN-IN KÁÀKIRI