CBN GBA ILE IFOWOPAMO SKYE, WON GBE E FUN POLARIS - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, September 23, 2018

CBN GBA ILE IFOWOPAMO SKYE, WON GBE E FUN POLARIS

Gomina ile ifowopamo orileede Naijiria, CBN, Godwin Emefiele ti pase pe ki ile ifowopamo Polaris tesiwaju isakoso ile ifowopamo Skye. Ojo Monde to n bo yii, iyen ojo kerinlelogun ni ase naa yoo bere.


Ojo Fraide to koja yi ni Emefiele fidi e mule fawon oniroyin niluu Eko pe banki apapo orileede yi, CBN ti gba iwe ase lowo ile ifowopamo Skye, won si ti gbe e fun ile ifowopamo Polaris lati tesiwaju.


Emefiele to tun je oga agba Nigeria Insurance Deposit Corporation (NDIC) je ko di mi mo pe ayipada yi ko le sakoba fawon to ti n lo ile ifowopamo Skye tele, di po be e, oruko ti won n je tele ni yoo yi pada, Polaris ni oruko tuntun naa.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI