ONI NI AYEYE OJO IBI WALE THOMPSON, GBAJUMO OLORIN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, September 23, 2018

ONI NI AYEYE OJO IBI WALE THOMPSON, GBAJUMO OLORIN

Bi e se n ka iroyin yi lowo, inu idunnu ati ayo ailopin ni gbajumo olorin nni, Ogbeni Wale Thompson tawon ololufe e mo si Mista Lalale Fraide nitori pe oni, ojo ketalelogun osu kesan an ni ayeye ojo ibi e.


Gbajumo olorin naa, to ti rin irin ajo kaakiri agbaye lati loo sere fawon ololufe e la gbo pe won si n ki ku ayeye ojo ibi naa bayii.

Bawon eeyan se n fi atejise ikiini lorisirisi ranse si Mista Lalale Fraide naa ni AWIKONKO naa n so fun un pe igba odun, odun kan ni.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI