WON FE E TA BANKI POLARIS LODUN 2020 - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, October 12, 2018

WON FE E TA BANKI POLARIS LODUN 2020


Ileese Asset Management Corporation of Nigeria (AMCON) ti so pe igbese lati ta banki Polaris lodun meji sasiko yi ti n lo lowo, ko si ni pee pari.

Ahmed Kuru, to je alaga ileese naa lo fidi oro yi mule nibi iforowero kan to se niluu Eko lai pe yii.

Be o ba gbagbe, osu to koja yi ni Polaris gbajoba banki Skye latari bi won se ri owo to ye ki won san san.

Kuru so pe awon ti baa won alakoso banki Polaris soro, won si ti fenuko pe kawon ta banki naa laarin odun meji sasiko yi.

PÍN-IN KÁÀKIRI