BABA AGBALAGBA FIPA B'OMODUN MARUN SUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, November 2, 2018

BABA AGBALAGBA FIPA B'OMODUN MARUN SUN

Ileese olopaa ipinle Benue ti rowo to baba agbaaya eni odun marundinlogoji (35), Haruna Shauibu to fipa fa idi omodunarun ya lagbegbe Wadata, niluu Makurdi


Ohun tá a gbo ni pe omo orukan lomodun marun ùn naa ti Haruna fipa fa idi e ya, ibi to sì ti n ko ibasun fún un lowo lasiri' é ti tu s'awọn araadugbo lowo.

Ogbeni Ukan Kurugh to je okan lara awon ajafeto-omoniyan lorilede yi to gbe oro naa s'AWIKONKO leti je ko ye wa pe  tesan olopaa ni Haruna wa titi dasiko ta a ko iroyin yi tan.


Ukan lo je ka mo ẹgbẹ awon agbejoro to je obinrin lagbaye, iyen International Federation of Women Lawyers (FIDA), eka tipinle Benue lo satona bọwọ olopaa se tẹ Haruna.

Bẹẹ lọ so pe lesekese tisele náà ti ṣẹlẹ ni won ti gbe ọmọ náà ló sì osibitu lati tọju é. Ọ tun je kó yé wa pé won ti foju Haruna bale ejo.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI