E WO OJU TISA TO N FIPA BAWON OMO KEKEEKE SUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, November 15, 2018

E WO OJU TISA TO N FIPA BAWON OMO KEKEEKE SUN

Owo olopaa ipinle Delta tiluu Warri ti te baale ile eni odun marundinlogoji kan, Lori Tuoyo ti won lo n fipa bawon omo kekeeke sun kaakiri ilu naa, paapaa awon akekoo tojo ori won ko tii ju odun mewaa lo.


Lori gba pe o je okan lara awon olukoni ti ileewe aladani kan to wa lagbegbe Jakpa/Ekpan niluu Warri, asiko to n fe e fipa bomodun mefa kan ta a foruko bo lasiri lo po lasiri e tu sawon eeyan lowo.

Lesekese ni won ti pariwo le e lori, ti won tun lu lalubami ko too di pe won loo fa le awon olopaa lowo, nibi to ti n gbategun bayii.

PÍN-IN KÁÀKIRI