O TAN O: IGBAKEJI GOMINA IPINLE SOKOTO KOWE FISE SILE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, November 14, 2018

O TAN O: IGBAKEJI GOMINA IPINLE SOKOTO KOWE FISE SILE

Alaaji Ahmed Aliyu to je igbakeji Gomina ipinle Sokoto ti kowe fiṣe sile latari bo se nipinu lati jade dupo gomina nipinle naa lodun 2019.


Gege ba a se gbo, kii se pe won dunkoko mo Ahmed Aliyu pe ko kowe fise naa sile, sugbon lati le je kipinu wa si imuse lo je kó gbé ìgbésẹ naa.

Abe àsìá ẹgbẹ oṣelu APC ni Aliyu ti fe é jade dupo gomina,to sì jẹ pe oga é télè, Gomina Waziri Tambuwal naa fe e pada sipo naa labẹ àsìá ẹgbẹ oṣelu PDP.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI