NITORI AWON MUSULUMI IJOBA APAPO KEDE ISINMI OLOJO KAN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, November 17, 2018

NITORI AWON MUSULUMI IJOBA APAPO KEDE ISINMI OLOJO KAN

Tusde ogunjo osu yii lawon Musulumi kaakiri agbaye yoo bere ayeye ayajo ojoobi Anobi Muhammed.

Related image

Ni bayii, ijoba apapo ti kede isinmi olojo kan fun ayeye naa, eyi to maa waye lojo Isegun to n bo yii. Ninu oro Minisita fun oro abele, Ajagunfeyinti  Abdulrahman Dambazau to se ikede ohun loruko ijoba apapo orile-ede yii lo ti ni ki awon Musulumi lo akoko naa lati fi wa ojuure Olorun, ki won si gbiyanju fi iwa daadaa jo Anobi.

O fi kun un pe, iwa ododo, iwa mimo, ifaaye-gba omlakeji ati ibagbepo alaafia ti Ojise nla ni lo fi gbayi julo lagbaye.

MAGASINNI ALORE

PÍN-IN KÁÀKIRI