Aaro ni Olori Ọlá gbe é sori ẹrọ ayelujara Instagram pe oun fe é sabewo sileewe gírámà toun ti jade lodun mokanla seyin, o loun ko le lọ l'ai je pe oun wo aso ileewe naa lo.
Lílọ ti Olori Ọlá fẹ é lo sileewe naa, ko seyin ti imurasile ayeye ojo ibi é to fe é se ni ola, ojo Abameta.
Idanilekoo lori ọrọ Ibalopọ (sex education) lo sì tún fi dawon lara ya.