ALAAFIN ỌYỌ GBALEJO BUHARI NILUU IBADAN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, January 26, 2019

ALAAFIN ỌYỌ GBALEJO BUHARI NILUU IBADAN

Ọla Eyitayọ, Ọyọ 

Ẹsẹ ko gbero ni gbogbo agbegbe Mapo niluu Ibadan lonii ọjọ kẹrinlelogun oṣu kinni, ọdun 2019 nigba ti Aarẹ orileede yi, Ọgagun Muhammadu Buhari; igbakeji ẹ, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo; Aṣiwaju ẹgbẹ oṣelu APC, Aṣiwaju Bọla Ahmẹd Tinubu; Alaga lapapọ, Kọmureedi Adams Ọshiọmolẹ; Gomina ipinlẹ Eko, Ọgbẹni Akinwunmi Ambọde atawọn agbaagba to fi mọ awọn adije ninu ẹgbẹ oṣelu naa balẹ siluufun ipolongo idibo, eyi ti yoo waye loṣu to m bọ.

Image may contain: 7 people, people smiling, people standing

Image may contain: 1 person, smiling, standing

Image may contain: 5 people, people smiling, people standing

Alaafin Ọyọ, Ọba Lamidi Ọlayiwọla Adeyẹmi, tawọn Ọba kaakiri ipinlẹ naa ni wọn wa nibi ipolongo naa, nibẹ ni Aarẹ Buhari ti rawọ ẹbẹ sawọn ọmọ ipinlẹ naa pe ki wọn jade sita ladi dibo foun, ki wọn si ma tun ṣe gba ẹgbẹ oṣelu PDP laaye mọ lorileede yi.

Image may contain: 2 people, people smiling, outdoor

Wọnyii ni diẹ lara awọn fọto eto naa.

Image may contain: one or more people, people standing, crowd and outdoor

Image may contain: 1 person, standing and on stage

Image may contain: 7 people, people on stage, crowd and outdoor


Image may contain: 5 people, people smiling

Image may contain: sky and outdoor

Image may contain: 7 people

Image may contain: 5 people, people smiling

Image may contain: one or more people, crowd and outdoor


Image may contain: one or more people, crowd and outdoor

Image may contain: one or more people, crowd and outdoor
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI