O TAN O: IJỌBA APAPỌ NI KI WỌN FAGILE ẸSUN TI WỌN FI KAN ADAJỌ AGBA ORILEEDE YI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, January 16, 2019

O TAN O: IJỌBA APAPỌ NI KI WỌN FAGILE ẸSUN TI WỌN FI KAN ADAJỌ AGBA ORILEEDE YI

BUHARI KO MỌ NNKANKAN NIPA ẸJỌ NAA TITI DI ỌJỌ SATIDE - ỌṢINBAJO

Buhari
Bo tilẹ jẹ pe ijọba apapọ orileede yi ti paṣẹ pe ki wọn fagile ẹsun ti wọn fi kan adajọ agba lorileede yi, Onidajọ Walter Onnoghen latari pe ko sọ awọn dukia to ni sita, ati pe o lọwọ ninu awọn ẹsun iwa gbigba abẹtẹlẹ lọwọ Gomina ipinlẹ Akwa-Ibọm, eyi ti ajọ EFCC fi kan an .

Igbakeji Aarẹ orileede Naijiria, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo ti pariwo sita fawọn ọmọ Naijiria pe Aarẹ Muhammadu Buhari ko mọ nnkankan nipa ẹsun ti won fi gbe adajọ agba tẹlẹri lorileede yi, Onidajọ Walter Onnoghen lọ sile ẹjọ Tribunal lọjọ Satide to kọja yi.

Ọṣinbajo lo sọrọ naa nibi ipade gbogboogbo ọlọjọ kan to ṣe pẹlu awọn akọroyin ori ẹrọ ayelujara lọjọ Wẹside ana niluu Abuja, iyẹn Online Publishers Association of Nigeria eyi ti wọn pe akori ẹ ni “Gbigba iroyin laaye lai figbakan bo ọkan ninu, ninu eto idibo ọdun 2019, (Free Press and objective reporting in the 2019 election year.)

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI